'N JE OLORUN TA AWON ENIYAN RE NU BI? Iwe-mimo wipe- KA MA RI I' Romu 11: 1- 2. A wo apeere ese bibeli yi ninu igbe aye Peteru ati Johannu ninu iwe Ise Awon Aposteli 4: 1-22. A si gba adura lati inu iwe Heberu 10: 23-24 wipe ki Olorun fun wa ni oore ofe lati di ijewo ireti wa mu sinsin ni aisiyemeji, nitori, olooto ni Olorun, eniti o se ileri. A gba a ni adura wipe, enu ope wa ko ni i kan. Gbogbo ihale esu lati pa wa ni enu mo ko ni se rere loruko Jesu.